Birthday Celebrations Happy Birthday, Alhaji Moruf Adeleye ifesowapo6 August 20250152 views Happy Birthday, Alhaji Moruf Adeleye Happy 76th birthday to our ever-youngest handsome Grandpa, Alhaji Moruf Adeleye Omo Olowu Oduru Omo Ajifegbesire Omo Amolese Bi Alari Alari Molese Owun Ole Omo Awuni Bikoje Arale Eni Omo Eni Mala Omo Mata Mata Mara tinkinje A Mo Eni Mala tan Lowu labenjo Ara Owu Kinsika Ara Owu Kindite Ara Owu Kinraro Awiimenukuro Ni Towu May Baba live longer in sound health and prosperity. Agba yin atunbo dale ninu Alafia ati Emi Gigun